A nilo owo (bi #30,000) lati ma ba iṣe yii lọ. Ti ẹ ba fẹ polowo ọja yin lori AwaYoruba tabi ẹ fẹ fi owo ran AwaYoruba lọwọ, ẹ kan si wa ni admin@awayoruba.com. E ṣe pupọ.
We need money (about #30,000) to continue this work. If you want to advertise on Awayoruba or you'd like to donate money to help this website, please contact us at admin@awayoruba.com. Thank you.

Body parts in Yoruba/ Eya ara ni eede Yoruba

Post Reply
User avatar
Rhomax
Reactions:
Posts: 156
Joined: Sun Mar 01, 2015 9:49 pm
Gender: Male

Body parts in Yoruba/ Eya ara ni eede Yoruba

Post by Rhomax » Fri Jan 20, 2017 5:03 pm

Aworan isale je aworan ti o yan nana awọn ẹya ara kankan ti awọn Yoruba fun ni orukọ. The picture below shows a labeled image of a boy with the body parts named in Yoruba.
eya ara Yoruba.jpg
Ẹya ara ni eede Yoruba
1. Hair - Irun
2. Eyes - Ojú
3. Ear - Etí
4. Mouth - Ẹnu
5. Nose - Imú
6. Teeth - Eyín
7. Head - Orí
8. Neck - Ọrùn
9. Arm - Apá
10. Hand - Ọwọ́
11. Shoulder - Ejìká
12. Elbow - Ìgúnpá
13. Fingers - Ìka
14. Chest - Àyà
15. Stomach - Ikùn
16. Thigh - Itan
17. Knee - Orúnkún
18. Ankle - Ọrùn ẹsẹ̀
19. Leg - Ẹsẹ̀
Rhomax na ni :D

sofunbej
Reactions:
Posts: 16
Joined: Thu Nov 10, 2016 11:29 am
Gender: Male

Re: Body parts in Yoruba/ Eya ara ni eede Yoruba

Post by sofunbej » Wed Jan 25, 2017 7:58 pm

I salute this work well done. But you should have used a black man instead of using oyibo man in the picture.

Mo ki Rhomax ku ise lori atejade yi. Sugbon iba daraju ti won ba lo aworan alawo dudu dipo oyibo ti won fi se apejuwe.

User avatar
Rhomax
Reactions:
Posts: 156
Joined: Sun Mar 01, 2015 9:49 pm
Gender: Male

Re: Body parts in Yoruba/ Eya ara ni eede Yoruba

Post by Rhomax » Thu Jan 26, 2017 1:40 pm

sofunbej wrote:
Wed Jan 25, 2017 7:58 pm
I salute this work well done. But you should have used a black man instead of using oyibo man in the picture.

Mo ki Rhomax ku ise lori atejade yi. Sugbon iba daraju ti won ba lo aworan alawo dudu dipo oyibo ti won fi se apejuwe.
Wallahi I didn't see a black one. Awon oyinbo ni mo nri lori ayelujara kakakiri. Thank you for the complement.
Rhomax na ni :D

User avatar
Rhomax
Reactions:
Posts: 156
Joined: Sun Mar 01, 2015 9:49 pm
Gender: Male

Re: Body parts in Yoruba/ Eya ara ni eede Yoruba

Post by Rhomax » Sun Jan 29, 2017 10:44 pm

oju.jpg
20. Eye brow - Igbengbereju
21. Eye lid - Ipenpeju
22. Eye balls - eyin oju
23. Eye lashes - irun oju/irun ipenpeju
Rhomax na ni :D

User avatar
Rhomax
Reactions:
Posts: 156
Joined: Sun Mar 01, 2015 9:49 pm
Gender: Male

Re: Body parts in Yoruba/ Eya ara ni eede Yoruba

Post by Rhomax » Mon Jan 30, 2017 10:27 pm

awon ika.jpg
awon ika.jpg (31.85 KiB) Viewed 1690 times
24. Thumb - Atampako
25. Index - Ika itoka
26. Middle finger - Ika aarin
27. Pinky finger - Omo ika/Omodinrin
28. Fingertip - Ori ika
29. Palm - Atele owo
30. Fingernails - Ekanna
Rhomax na ni :D

User avatar
orisun
Reactions:
Posts: 7
Joined: Thu Mar 12, 2015 11:32 am
Gender: None specified

Re: Body parts in Yoruba/ Eya ara ni eede Yoruba

Post by orisun » Tue Feb 07, 2017 3:10 pm

31. Bebe idi - Waist
32. Ibadi (Iba idi) - Hips
33. Idi - Buttocks
34. Aiya tabi Ige - Chest
35. Oyan tabi Omu - Breasts usually used for females.
36. Oko - Penis
37. Navel - Idodo
38. Epon - Scrotum
39. Woropon/Horopon - Testes
40. Obo - Vagina

User avatar
Eight
Reactions:
Posts: 114
Joined: Thu Mar 12, 2015 11:37 am
Gender: Male

Re: Body parts in Yoruba/ Eya ara ni eede Yoruba

Post by Eight » Mon Feb 20, 2017 4:14 pm

41. Tongue = Ahon
42. Erigi = Gum
43. Orun owo = Wrist
44. Atele ese - Under the feet
45. Awuje - Center of the head
46. Paari - Temple
Believe my date of birth at your own peril.

Guest
Reactions:
Gender: None specified

Re: Body parts in Yoruba/ Eya ara ni eede Yoruba

Post by Guest » Fri Mar 03, 2017 4:09 pm

47. Ẹrẹkẹ/Ẹkẹ - Cheeks

Guest
Reactions:
Gender: None specified

Re: Body parts in Yoruba/ Eya ara ni eede Yoruba

Post by Guest » Thu Jul 20, 2017 10:54 am

48. Ori Ekun - Knee cap

Post Reply
  • Similar Topics
    Replies
    Views
    Last post

Who is online

Users browsing this forum: No registered users and 16 guests