A nilo owo (bi #30,000) lati ma ba iṣe yii lọ. Ti ẹ ba fẹ polowo ọja yin lori AwaYoruba tabi ẹ fẹ fi owo ran AwaYoruba lọwọ, ẹ kan si wa ni admin@awayoruba.com. E ṣe pupọ.
We need money (about #30,000) to continue this work. If you want to advertise on Awayoruba or you'd like to donate money to help this website, please contact us at admin@awayoruba.com. Thank you.

Numbers in Yoruba/Onka Yoruba

Post Reply
User avatar
Mayowa
Reactions:
Posts: 538
Joined: Sun Mar 01, 2015 3:23 pm
Gender: Male

Numbers in Yoruba/Onka Yoruba

Post by Mayowa » Mon Feb 27, 2017 3:58 pm

Numbering in Yoruba/Onka Yoruba
Basic Numbering Onka Lasan Quantitative Numbering Onka kika
1 Eni One Ọkan
2 Eji Two Meji
3 Ẹta Three Mẹta
4 Ẹrin Four Mẹrin
5 Arun Five Marun
6 Ẹfa Six Mẹfa
7 Eje Seven Meje
8 Ẹjọ Eight Mẹjọ
9 Ẹsan Nine Mẹsan
10 Ẹwa Ten Mẹwa
11 Ọkanla Eleven Mọkanla
12 Ejila Twelve Mejila
13 Ẹtala Thirteen Mẹtala
14 Ẹrinla Fourteen Mẹrinla
15 Ẹẹdogun Fifteen Mẹẹdogun
16 Ẹrindilogun Sixteen Mẹrindilogun
17 Ẹtadilogun Seventeen Mẹtadilogun
18 Ejidilogun Eighteen Mejidilogun
19 Ọkandilogun Nineteen Mọkandilogun
20 Ogun Twenty Ogun
21 Okanlelogun Twenty-one Mọkanlelogun
22 Ejilelogun Twenty-two Mejilelogun
23 Ẹtalelogun Twenty-three Mẹtalelogun
24 Ẹrinlelogun Twenty-four Mẹrinlelogun
25 Ẹdọgbọn Twenty-five Mẹdọgbọn
E parapo mo wa ki e si pe awon ore yin na wa parapo mo wa. Register with us and invite your friends too.

User avatar
Mayowa
Reactions:
Posts: 538
Joined: Sun Mar 01, 2015 3:23 pm
Gender: Male

Re: Numbers in Yoruba/Onka Yoruba

Post by Mayowa » Tue Feb 28, 2017 10:24 am

Numbering in Yoruba/Onka Yoruba
Basic Numbering Onka Lasan Quantitative Numbering Onka kika
26 Ẹrindilọgbọn Twenty-six Mẹrindilọgbọn
27 Ẹtadilọgbọn Twenty-seven Mẹtadilọgbọn
28 Ejidilọgbọn Twenty-eight Mejidilọgbọn
29 Okandilọgbọn Twenty-nine Mọkandilọgbọn
30 Ọgbọn Thirty Ọgbọn
35 Arundilogoji Thirty-five Marundilogoji
40 Ogoji/Oji Forty Ogoji/Oji
45 Arundiladọta Forty-five Marundiladọta
50 Adọta Fifty Adọta
55 Arundilọgọta Fifty-five Marundilọgọta
60 Ọgọta/Ọta Sixty Ọgọta/Ọta
65 Arundiladọrin Sixty-five Marundiladọrin
70 Adọrin Seventy Adọrin
75 Arundilọgọrin Seventy-five Marundiladọrin
80 Ọgọrin/Ọrin Eighty Ọgọrin
85 Arundiladọrun Eighty-five Marundiladọrun
90 Adọrun Ninety Adọrun
95 Arundilọgọrun Ninety-five Marundilọgọrun
100 Ọgọrun One hundred Ọgọrun/Ọrun
200 Igba Two hundred Igba
300 Ọdunrun Three hundred Ọdunrun
E parapo mo wa ki e si pe awon ore yin na wa parapo mo wa. Register with us and invite your friends too.

User avatar
Mayowa
Reactions:
Posts: 538
Joined: Sun Mar 01, 2015 3:23 pm
Gender: Male

Re: Numbers in Yoruba/Onka Yoruba

Post by Mayowa » Tue Feb 28, 2017 10:58 am

Numbering in Yoruba/Onka Yoruba
Basic Numbering Onka Lasan Quantitative Numbering Onka kika
400 Irinwo Four hundred Irinwo
500 Ẹdegbẹta Five hundred Ẹdẹgbẹta
600 Ẹgbẹta Six hundred Ẹgbẹta
700 Ẹdẹgbẹrin Seven hundred Ẹdẹgbẹrin
800 Ẹgbẹrin Eight hundred Ẹgbẹrin
900 Ẹdẹgbẹrun Nine hundred Ẹdẹgbẹrun
1000 Ẹgbẹrun One thousand Ẹgbẹrun
2000 Ẹgbawa Two thousand Ẹgbawa
3000 Ẹgbẹdogun Three thousand Ẹgbẹdogun
4000 Ẹgbaji Four thousand Ẹgbaji
5000 Ẹdẹgbata Five thousand Ẹdẹgbata
6000 Ẹgbata Six thousand Ẹgbata
7000 Ẹdẹgbarin Seven thousand Ẹdẹgbarin
8000 Ẹgbarin Eight thousand Ẹgbarin
9000 Ẹdẹgbarun Nine thousand Ẹdẹgbarun
10000 Ẹgbarun Ten thousand Ẹgbarun
20000 Ọkẹ kan Twenty thousand Ọkẹ kan
E parapo mo wa ki e si pe awon ore yin na wa parapo mo wa. Register with us and invite your friends too.

s4035
Reactions:
Gender: None specified

Re: Numbers in Yoruba/Onka Yoruba

Post by s4035 » Mon Oct 02, 2017 8:42 pm

Mayowa wrote:
Tue Feb 28, 2017 10:24 am
Numbering in Yoruba/Onka Yoruba
Basic Numbering Onka Lasan Quantitative Numbering Onka kika
26 Ẹrindilọgbọn Twenty-six Mẹrindilọgbọn
27 Ẹtadilọgbọn Twenty-seven Mẹtadilọgbọn
28 Ejidilọgbọn Twenty-eight Mejidilọgbọn
29 Okandilọgbọn Twenty-nine Mọkandilọgbọn
30 Ọgbọn Thirty Ọgbọn
35 Arundilogoji Thirty-five Marundilogoji
40 Ogoji/Oji Forty Ogoji/Oji
45 Arundiladọta Forty-five Marundiladọta
50 Adọta Fifty Adọta
55 Arundilọgọta Fifty-five Marundilọgọta
60 Ọgọta/Ọta Sixty Ọgọta/Ọta
65 Arundiladọrin Sixty-five Marundiladọrin
70 Adọrin Seventy Adọrin
75 Arundilọgọrin Seventy-five Marundiladọrin
80 Ọgọrin/Ọrin Eighty Ọgọrin
85 Arundiladọrun Eighty-five Marundiladọrun
90 Adọrun Ninety Adọrun
95 Arundilọgọrun Ninety-five Marundilọgọrun
100 Ọgọrun One hundred Ọgọrun/Ọrun
200 Igba Two hundred Igba
300 Ọdunrun Three hundred Ọdunrun

Post Reply
  • Similar Topics
    Replies
    Views
    Last post

Who is online

Users browsing this forum: No registered users and 15 guests