A nilo owo (bi #30,000) lati ma ba iṣe yii lọ. Ti ẹ ba fẹ polowo ọja yin lori AwaYoruba tabi ẹ fẹ fi owo ran AwaYoruba lọwọ, ẹ kan si wa ni admin@awayoruba.com. E ṣe pupọ.
We need money (about #30,000) to continue this work. If you want to advertise on Awayoruba or you'd like to donate money to help this website, please contact us at admin@awayoruba.com. Thank you.

Names of some animals and their Yoruba meanings

Post Reply
Agboola gbenga
Reactions:
Posts: 31
Joined: Thu Sep 08, 2016 9:51 am
Gender: Male

Names of some animals and their Yoruba meanings

Post by Agboola gbenga » Wed May 31, 2017 7:39 am

Cobra - Ọká
Ox/Bull - Màlúù
Spit-Snake - Ṣèbé
Dog - Ajá
Hedgehog - líìlí
Grass cutter - Òyà
Pangolin - Akika
Crocodile - Ọọ̀nì
Alligator -Ahọ́nríhọ́n
Pig - Ẹlẹ́dẹ̀
Vulture: Igún/Gúnnugún/Gúrugú,/Àkàlà/Àkàlàmàgbò
Wood-Carrier-Aringiṣẹ́gi
Hawk - Àṣá
Eagle - Àwòdì
Parrot: Odídẹrẹ́/Aiyékòótọ́
Palm-Bird *** Ologiri
A species of Bird- Olofẹrẹ
Sparrow - Ológoṣẹ́
Peacock - Ọ̀kín
Owl - Òwìwí
Squirrel - Ọ̀kẹ́rẹ́
Rabbit - Ehoro
Crickets - Okinrin
Pouch Rat - Òkété
Wild Goat - Edu
A species of Deer- Ekùlù
Shark - Akurakúdà
Whale - Àbùnbùtán
Rat/Mouse - Eku/Èkúté
Earthworm - Ekòló
Snake - Ejò
Birds - Ęyę
Sing Bird - Ẹyẹ-Orin
Partridge - Àparò
Horse - Ẹṣin
Donkey - Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́
Camel - Ràkúnmí
Ass - Ìbákasíẹ
Bat - Àdán
Pelican - Ẹyẹ-Ofu
Water-bird - Osin
Dove - Àdàbà
Viper - Paramọ́lẹ̀
Sea-Gulls - Pẹju-pẹju
Yellow-haired Monkey - Sọmídọlọ́tí/Oloyo
Sea-Bird - Yanja-yanja
Mosquito: Ẹfọn/Yànmù-yánmú
A species of Beetles - Yánrínbo
Raven - Ẹyẹ ìwò
Snail - Ìgbín/Aginniṣọ
Freshwater Snail: Ìṣáwùrú
Antelope - Ìgalà
Steer: Ẹgbọọrọ-Akọ Màlúù
Trout - Ẹja
Buffalo - Ẹfọ̀n
Monkey - Ọ̀bọ
Ape - Ẹdun
Lizard - Aláǹgbá
Lobster - Alakasa
Boa Constrictor - Erè
Boar/Warthog -Ẹlẹ́dẹ̀-Igbó /Ìmàdò
Gorilla/Ape: Ìnàkí/Ìnọ̀kí/Irọ̀
Chimpanzee - Elégbèdè
Phython - Òjòlá
Electric Fish - Òjijí
Scorpion - Ojogan/Àkeekèé
Toad - Kọ̀nkọ̀
Frog - Ọ̀pọ̀lọ́
Antelope: Egbin/Ìgalà/Ętu
Tick/Flee: Eégbọn
Bedbug - Ìdun
Hippopotamus -Erinmi/Erin-Omi
Rhinoceros - Ẹranko bí Ìmàdò
Reynard/Fox - Kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀
Hyena/Wolf - Ìkokò
Giraffe - Àgbáǹréré
Cow - Abo-Màlúù
Crab - Akàn
Wild Pigeon - Oriri
Porcupine - Oorẹ/Eerẹ/Ojigbọn
Black-Ants - Tanipẹ́pẹ́
Centipede - Tani-nṣán-ẹ̀kọ/Taninṣánkọ
Millipede - Ọ̀kùn
Goanna -Awọ́nrínwọ́n
Insect - Kòkòrò
Chick -Òròmọ-Adìẹ
Nocturnal Animal -Àjàù
Hound - Ajá-Ọdẹ -
Elephant - Erin/Àjànàkú
Sheep - Àgùntàn
Ram - Àgbò
Woodcock - Agbe
A species of Woodcock - Àlùkò
White-feathered Bird - Lékèélékèé
Chamelon -Ọ̀gà/Alágẹmọ
Crane-Bird - Akọ
Ostrich - Ògòǹgò
White-Ant - Ikán, Ìkamùdù
Tortoise - Ìjàpá
Tiger - Ẹkùn
Leopard - Amọ̀-tẹ́kùn
Lion - Kìnìún
Pigeon - Ẹyẹlé
Pig/Swine - Ẹlẹ́dẹ̀
Eagle - Ìdì
Guinea-Fowl -Awó/Ẹtù
Guinea Pig - Ẹmọ́-Ilé
Jelly-Fish - Ẹja odò
A species of Bird - Àfẹ̀rẹ̀gbòjò/Àfẹ̀-ìmòjò
Spider - Aláǹtakùn
Butterfly - Labalábá
Bee - Oyin
Cockroach -Aáyán
Cricket - Ìrẹ̀
Crab - Akàn
Housefly - Eṣinṣin/Eṣin
Gnats - Kokoro-Ojúọtí
Wall-Gecko - Ọmọ-onílé
Mouse - Ẹ̀lírí
Colt/Young Horse - Agódóńgbó
Woodpecker - Àkókó
Palm-Bird - Ẹ̀gà
Insect - Ipin/Kòkòrò
Red-Ant - Abóníléjọpọ́n
Cat - Ológbo/Ológìnní
Civet-cat - Ętà
Zebra - Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́-Abilà
Lice - Iná-Orí
Hind -Abo-Àgbọ̀nrín
Turkey - Tòlótòló
Swallow - Alápàáǹdẹ̀dẹ̀
Kine - Abo-Màlúù
Stallion - Akọ-Ẹṣin
Gadfly - Irù/Eṣinṣin-ńlá
Duck - Pẹ́pẹ́yẹ
Jackal - Akátá/Ajákò
And many more ....


AGBOOLA GBENGA OMO ORA-IGBOMINA OSUN STATE

Baba Owe
Reactions:
Gender: None specified

Re: NAMES OF SOME ANIMALS AND THEIR YORUBA MEANING

Post by Baba Owe » Wed May 31, 2017 9:22 am

Eleyi gidi gan o. Kini awonriwon gan? Ni viewtopic.php?f=12&t=149&p=1633&hilit=awonriwon#p1633 eyan kan ni newt ni awonriwon.
Awonriwon seems to be confusing us all. That Goanna even looks like what we call alegba.

User avatar
Mayowa
Reactions:
Posts: 538
Joined: Sun Mar 01, 2015 3:23 pm
Gender: Male

Re: Names of some animals and their Yoruba meanings

Post by Mayowa » Wed May 31, 2017 3:55 pm

Thank you for the beautiful post @Agboola Gbenga.
A dupe lowo yin lopolopo.
E parapo mo wa ki e si pe awon ore yin na wa parapo mo wa. Register with us and invite your friends too.

Tayo
Reactions:
Gender: None specified

Re: Names of some animals and their Yoruba meanings

Post by Tayo » Mon Jun 12, 2017 3:09 pm

Alligator is ahonrihon in Yoruba

Guest
Reactions:
Gender: None specified

Re: Names of some animals and their Yoruba meanings

Post by Guest » Mon Jun 12, 2017 3:36 pm

Correction:
Spit Snake is also cobra = Sebe
Python = Oka

Post Reply
  • Similar Topics
    Replies
    Views
    Last post

Who is online

Users browsing this forum: No registered users and 16 guests