A nilo owo (bi #30,000) lati ma ba iṣe yii lọ. Ti ẹ ba fẹ polowo ọja yin lori AwaYoruba tabi ẹ fẹ fi owo ran AwaYoruba lọwọ, ẹ kan si wa ni admin@awayoruba.com. E ṣe pupọ.
We need money (about #30,000) to continue this work. If you want to advertise on Awayoruba or you'd like to donate money to help this website, please contact us at admin@awayoruba.com. Thank you.

I need ten (10) Àló Àpamò

Ibeere ati awon amoran ti a le fi mu ibi dara si.
Post Reply
Michael
Reactions:
Posts: 1
Joined: Mon May 01, 2017 8:26 pm
Gender: None specified

I need ten (10) Àló Àpamò

Post by Michael » Mon May 01, 2017 8:39 pm

Good evening house. Pls, I need Ten (10) àló àpamò. God bless you.

User avatar
nomba1
Reactions:
Posts: 56
Joined: Thu Mar 12, 2015 11:28 am
Gender: Male

Re: Àló Àpamò

Post by nomba1 » Mon May 01, 2017 10:20 pm

Michael wrote:
Mon May 01, 2017 8:39 pm
Good evening house. Pls, I need Ten (10) àló àpamò. God bless you.
1. Mo n lo si Oyo mo koju si Oyo, mo n bo lati Oyo mo koju si Oyo, kini o?
2. Akuko baba mi lailai, akuko baba mi lailai, owo ni n je ki nje agbado, kini o?
3. Kini n ba oba jeun ti ki n yo sibi?
4. Kini n koja ni iwaju ile oba ti ki n ki oba?
5. Okun n ho yaa, osa n ho yaa, omo buruku ti ori bo, kini o?
:mrgreen: :mrgreen: :mrgreen: :mrgreen: :mrgreen: :D :lol: :lol: :lol:

Onibere
Reactions:
Gender: None specified

Re: Àló Àpamò

Post by Onibere » Tue May 02, 2017 10:03 am

Opa tinrin kanle o kan orun, kini o?

alejo
Reactions:
Gender: None specified

Re: Àló Àpamò

Post by alejo » Tue May 02, 2017 10:06 am

Ko ni eegun amo ti o ba te mole wa tiro.

Ogbeni
Reactions:
Gender: None specified

Re: Àló Àpamò

Post by Ogbeni » Tue May 02, 2017 1:17 pm

-Ikoko rugudu fehin ti igbo

-Ko ni apa ko ni ese, o ni n gbomo wa

roger
Reactions:
Gender: None specified

Re: Àló Àpamò

Post by roger » Wed May 03, 2017 1:26 pm

Ki ni nba oba jeun ti ko ki npa ile mo?

Ki ni nkan oba niko laise pele?

Ki ni npa oba lekun lai na oba?

That's all.

User avatar
Apa
Reactions:
Posts: 64
Joined: Thu Mar 12, 2015 11:35 am
Gender: None specified

Re: Àló Àpamò

Post by Apa » Wed May 10, 2017 11:52 am

nomba1 wrote:
Mon May 01, 2017 10:20 pm

1. Mo n lo si Oyo mo koju si Oyo, mo n bo lati Oyo mo koju si Oyo, kini o?
2. Akuko baba mi lailai, akuko baba mi lailai, owo ni n je ki nje agbado, kini o?
3. Kini n ba oba jeun ti ki n yo sibi?
4. Kini n koja ni iwaju ile oba ti ki n ki oba?
5. Okun n ho yaa, osa n ho yaa, omo buruku ti ori bo, kini o?
Answers:
1. Ilu
2. Kolo
3. Esinsin
4. Agbara
5. Omorogun
Onibere wrote:
Tue May 02, 2017 10:03 am
Opa tinrin kanle o kan orun, kini o?
Ojo
alejo wrote:
Tue May 02, 2017 10:06 am
Ko ni eegun amo ti o ba te mole wa tiro.
Igbe
Ogbeni wrote:
Tue May 02, 2017 1:17 pm
-Ikoko rugudu fehin ti igbo

-Ko ni apa ko ni ese, o ni n gbomo wa
Igbin

I don't know the second one

User avatar
Mayowa
Reactions:
Posts: 538
Joined: Sun Mar 01, 2015 3:23 pm
Gender: Male

Re: Àló Àpamò

Post by Mayowa » Sun May 21, 2017 5:42 pm

Apa wrote:
Wed May 10, 2017 11:52 am
nomba1 wrote:
Mon May 01, 2017 10:20 pm

1. Mo n lo si Oyo mo koju si Oyo, mo n bo lati Oyo mo koju si Oyo, kini o?
2. Akuko baba mi lailai, akuko baba mi lailai, owo ni n je ki nje agbado, kini o?
3. Kini n ba oba jeun ti ki n yo sibi?
4. Kini n koja ni iwaju ile oba ti ki n ki oba?
5. Okun n ho yaa, osa n ho yaa, omo buruku ti ori bo, kini o?
Answers:
1. Ilu
2. Kolo
3. Esinsin
4. Agbara
5. Omorogun
Onibere wrote:
Tue May 02, 2017 10:03 am
Opa tinrin kanle o kan orun, kini o?
Ojo
alejo wrote:
Tue May 02, 2017 10:06 am
Ko ni eegun amo ti o ba te mole wa tiro.
Igbe
Ogbeni wrote:
Tue May 02, 2017 1:17 pm
-Ikoko rugudu fehin ti igbo

-Ko ni apa ko ni ese, o ni n gbomo wa
Igbin

I don't know the second one
@apa
-Ko ni apa ko ni ese, o ni n gbomo wa
Ẹni ni o.
E parapo mo wa ki e si pe awon ore yin na wa parapo mo wa. Register with us and invite your friends too.

User avatar
nomba1
Reactions:
Posts: 56
Joined: Thu Mar 12, 2015 11:28 am
Gender: Male

Re: Àló Àpamò

Post by nomba1 » Wed May 31, 2017 11:35 am

Apa wrote:
Wed May 10, 2017 11:52 am
nomba1 wrote:
Mon May 01, 2017 10:20 pm

2. Akuko baba mi lailai, akuko baba mi lailai, owo ni n je ki nje agbado, kini o?
Answers:
2. Kolo
Answer: Obinrin
Obinrin ni ko ki n se kolo.
:mrgreen: :mrgreen: :mrgreen: :mrgreen: :mrgreen: :D :lol: :lol: :lol:

Victor
Reactions:
Gender: None specified

Re: Àló Àpamò

Post by Victor » Thu Sep 07, 2017 12:28 pm

[quote=Onibere post_id=1756 time=1493715829]
Opa tinrin kanle o kan orun, kini o?
[/quote] oojo ni o

Guest
Reactions:
Gender: None specified

Re: Àló Àpamò

Post by Guest » Thu Sep 07, 2017 12:30 pm

[quote=Onibere post_id=1756 time=1493715829]
Opa tinrin kanle o kan orun, kini o?
[/quote] oojo ni o

User avatar
osuolale.king
Reactions:
Posts: 2
Joined: Tue Nov 07, 2017 8:39 pm
Gender: None specified

Re: I need ten (10) Àló Àpamò

Post by osuolale.king » Tue Nov 07, 2017 9:04 pm

Bi won ba won ba wu iwa aburu won o pa iro momi kini oruko mi? (idahun)ki se mi ni o

User avatar
osuolale.king
Reactions:
Posts: 2
Joined: Tue Nov 07, 2017 8:39 pm
Gender: None specified

Re: I need ten (10) Àló Àpamò

Post by osuolale.king » Tue Nov 07, 2017 9:09 pm

Iya dudu ko akisa kora lo si orun (idahun)Amala dudu ati efo nlo si ona ofun

Post Reply

Who is online

Users browsing this forum: No registered users and 4 guests